Hosea 12:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èmi ni OLUWA Ọlọrun rẹ láti ilẹ̀ Ijipti; n óo tún mú ọ pada gbé inú àgọ́, bí àwọn ọjọ́ àjọ ìyàsọ́tọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati emi, Oluwa Ọlọrun rẹ lati ilẹ̀ Egipti wá, yio si tún mu ọ gbe inu agọ, bi ọjọ ajọ-ọ̀wọ wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run rẹ; ẹni tí ó mu ọ jáde wá láti ilẹ̀ Éjíbítì; èmi yóò tún mú yín gbé nínú àgọ́ bí i ọjọ́ àjọ mímọ́ wọ̀n ọn nì