Hosea 13:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Pẹlu ibinu, ni mo fi fun yín ní àwọn ọba yín, ìrúnú ni mo sì fi mú wọn kúrò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi fun ọ li ọba ni ibinu mi, mo si mu u kuro ni irúnu mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí èyí nínú ìbínú mi ni mo fún un yín lọ́ba Ninú ìbínú gbígbóná mi, Mo sì mú un kúrò