Hosea 13:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ṣugbọn nígbà tí ẹ jẹun yó tán, ẹ̀ ń gbéraga, ẹ gbàgbé mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi a ti bọ́ wọn, bẹ̃ni nwọn yó; nwọn yó, nwọn si gbe ọkàn wọn ga; nitorina ni nwọn ṣe gbagbe mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ni ìtẹ́lọ́rùn nígbà tí mo fún wọn ní oúnjẹ Nígbà tí wọ́n ní ìtẹ́lọ́rùn tan wọ́n di agbéraga Nígbà náà ni wọ́n sì gbàgbé mi.