Hosea 13:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, bíi kinniun ni n óo ṣe si yín, n óo lúgọ lẹ́bàá ọ̀nà bí àmọ̀tẹ́kùn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li emi o ṣe dabi kiniun si wọn; emi o si ma ṣọ wọn bi ẹkùn li ẹ̀ba ọ̀na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún Èmi yóò farapamọ́ dè wọ́n lọ́nà bí i ẹkùn.