Hosea 14:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ pada sọ́dọ̀ OLUWA, kí ẹ sọ pé, “Mú ẹ̀ṣẹ̀ wa kúrò, gba ohun tí ó dára a óo sì máa yìn ọ́ lógo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mu ọ̀rọ pẹlu nyin, ẹ si yipadà si Oluwa: ẹ wi fun u pe, Mu aiṣedẽde gbogbo kuro, si fi ore-ọfẹ gbà wa: bẹ̃ni awa o fi ọmọ malu ète wa san a fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ gba ọ̀rọ̀ OLÚWA gbọ́, Kí ẹ sì yípadà sí OLÚWA. Ẹ sọ fún un pé: “Darí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá kí o sì fi oore ọ̀fẹ́ gbà wá, kí àwa kí ó lè fí ètè wa sán-an fún ọ