Hosea 2:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé, n óo gba orúkọ Baali kúrò lẹ́nu rẹ̀, kò sì ní dárúkọ rẹ̀ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori emi o mu orukọ awọn Baali kuro li ẹnu rẹ̀, a kì yio si fi orukọ wọn ranti wọn mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mú orúkọ, àwọn òrìṣà Báálì kúrò lẹ́nu rẹ̀; ìwọ kò sì ní rí orúkọ òrìṣà Báálì pè mọ́