Hosea 2:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ilẹ̀ yóo sì dáhùn adura ọkà, ati ti waini ati ti òróró. Àwọn náà óo sì dáhùn adura Jesireeli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ yio si dá ọkà, ati ọti-waini, ati ororo, li ohùn; nwọn o si dá Jesreeli li ohùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ náà yóò sì dá ọkà, wáìnì tuntun àti òróró lóhùn Gbogbo wọn ó sì dá Jésírẹ́lì lóhùn.