Hosea 3:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, mo rà á ní ṣekeli fadaka mẹẹdogun ati ìwọ̀n ọkà baali kan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni mo rà a fun ara mi ni fadakà mẹ̃dogun, ati homeri barli kan pẹlu ãbọ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, mo sì rà á padà ní ṣékélì fàdákà mẹ́ẹ̀dógún (15) àti Ómírì kan àti lẹ́tíkì báálì kan.