Hosea 4:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹgbẹ́ ọ̀mùtí ni wọ́n, wọ́n fi ara wọn fún ìwà àgbèrè, ìtìjú yá wọn lára ju ògo lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun mimu wọn di kikan: nwọn ṣe agbère gidigidi; awọn olori rẹ̀ fẹ itìju, ẹ bun u li ayè.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tán wọ́n tún tẹ̀ṣíwájú nínú àgbèrè àwọn olórí wọn fẹ́ràn ohun ìtìjú ju ohun ìyìn lọ.