Hosea 4:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ẹ óo fẹsẹ̀ kọ lojumọmọ, ẹ̀yin wolii pàápàá yóo kọsẹ̀ lóru, n óo sì pa Israẹli, ìyá yín run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o si ṣubu li ọ̀san, woli yio si ṣubu pẹlu rẹ li alẹ, emi o si ké iya rẹ kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ ń ṣubú lọ́sàn-án àti lóru àwọn wòlíì yín sì ń ṣubú pẹ̀lúu yín Èmi ó pa ìyá rẹ run