Hosea 5:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin alufaa! Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, ẹ̀yin ọmọ Israẹli ati ẹ̀yin ìdílé ọba! Ẹ̀yin ni ìdájọ́ náà dé bá; nítorí ẹ dàbí tàkúté ní Misipa, ati bí àwọ̀n tí a ta sílẹ̀ lórí òkè Tabori.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ gbọ́ eyi, ẹnyin alufa: si tẹtilelẹ ẹnyin ile Israeli; ki ẹ si gbọ́, ile ọba na; nitori idajọ kàn nyin, nitoriti ẹnyin ti jẹ ẹgẹ́ si Mispa, àwọn ti a nà silẹ lori Tabori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yìn àlùfáà! Ẹ fetí sílẹ̀ ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì! Ẹ gbọ́, ẹ̀yìn ilé ọba! Ìdájọ́ yìí kàn yín: Ẹ ti jẹ́ ẹ̀bìtì ní Mísípà Àwọ̀n ti a nà sìlẹ̀ lórí Tábórì