Hosea 6:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ẹ̀yin ará Juda pàápàá, mo ti dá ọjọ́ ìjìyà yín sọ́nà, fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ̀ ń dá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ Juda pẹlu, on ti gbe ikorè kalẹ fun ọ, nigbati mo ba yi igbekun awọn enia mi padà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àti fún ìwọ, Júdà A ti yan ọjọ́ pẹ̀lú ìkórè rẹ “Nígbà tí mo bá fẹ́ dá ohun ìní àwọn ènìyàn mi padà,