Hosea 6:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn OLUWA wí pé, “Kí ni kí n ti ṣe ọ́ sí, ìwọ Efuraimu? Kí ni kí n ti ṣe ọ́ sí, ìwọ Juda? Ìfẹ́ yín dàbí ìkùukùu òwúrọ̀, ati bí ìrì tíí yára á gbẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu, kili emi o ṣe si ọ? Juda, kili emi o ṣe si ọ? nitori ore nyin dàbi ikuku owurọ̀, ati bi ìri kùtukùtu ti o kọja lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kí ni èmi ó ṣe pẹ̀lú rẹ, Éfúráímù? Kí ni èmi ó ṣe pẹ̀lú rẹ, Júdà? Ìfẹ́ rẹ dàbí ìkùùku òwúrọ̀ bí ìrì ìdájí tí ó kọjá lọ kíákíá.