Hosea 7:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Efuraimu dàbí ẹyẹ àdàbà, ó jẹ́ òmùgọ̀ ati aláìlóye, ó ń pe Ijipti fún ìrànlọ́wọ́, o ń sá tọ Asiria lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu pẹlu dabi òpe adàba ti kò li ọkàn; nwọn kọ si Egipti, nwọn lọ si Assiria.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Éfúráímù dàbí àdàbà tó rọrùn láti tàn jẹ àti aláìgbọ́n tó wá ń pé Éjíbítì nísinsìn yìí tó sì tún ń padà lọ si Ásíríà.