Hosea 7:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn wọn kò rò ó pé mò ń ranti gbogbo ìwà burúkú àwọn. Ìwà burúkú wọn yí wọn ká, ẹ̀ṣẹ̀ wọn sì wà níwájú mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kò si rò li ọkàn wọn pe, emi ranti gbogbo ìwa-buburu wọn: nisisiyi iṣẹ ara wọn duro yi wọn ka; nwọn wà niwaju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n wọn kò mọ̀ pé mo rántí gbogbo ìwà búburú wọn: Ẹ̀ṣẹ̀ wọn gbé wọn mì pátapáta wọ́n wà níwájú mi nígbà gbogbo.