Hosea 7:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọjọ́ tí ọba ń ṣe àjọyọ̀, àwọn ìjòyè mu ọtí àmupara, títí tí ara wọn fi gbóná; ọba pàápàá darapọ̀ mọ́ àwọn ẹlẹ́yà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ ọba wa, awọn ọmọ-alade ti fi oru ọti-waini mu u ṣaisàn; o nà ọwọ́ rẹ̀ jade pẹlu awọn ẹlẹgàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ àjọ̀dún ọba wa wáìnì mú ara àwọn ọmọ aládé gbóná ó sì darapọ̀ mọ́ àwọn oníyẹ̀yẹ́.