Hosea 7:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Efuraimu darapọ̀ mọ́ àwọn eniyan tí wọ́n yí wọn ká, Efuraimu dàbí àkàrà tí kò jinná dénú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu, on ti dà ara rẹ̀ pọ̀ mọ awọn enia na; Efraimu ni akàra ti a kò yipadà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Éfúráímù ti darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn náà; Éfúráímù jẹ́ àkàrà tí a kò yípadà