Hosea 8:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Israẹli ti kọ ohun rere sílẹ̀; nítorí náà, àwọn ọ̀tá yóo máa lépa wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Israeli ti gbe ohunrere sọnù; ọta yio lepa rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ísírẹ́lì ti kọ ohun tí ó dára sílẹ̀ ọ̀tá yóò sì máa lépa rẹ̀