Hosea 8:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Oriṣa ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù kì í ṣe Ọlọrun, iṣẹ́ ọwọ́ eniyan ni, a óo sì rún ti Samaria wómúwómú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori lati ọdọ Israeli wá li o ti ri bẹ̃ pẹlu; oniṣọ̀na li o ṣe e; nitorina on kì iṣe Ọlọrun: ṣugbọn ọmọ malu Samaria yio fọ tũtũ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísírẹ́lì ni wọ́n ti wá! Ère yìí—agbẹ́gilére ló ṣe é Àní ère Samáríà, ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́.