Hosea 9:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo rí àwọn ọmọ Efuraimu bí ẹran àpajẹ; Efuraimu gbọdọ̀ kó àwọn ọmọ rẹ̀ jáde fún pípa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu, bi mo ti ri Tirusi, li a gbìn si ibi daradara: ṣugbọn Efraimu yio bi ọmọ rẹ̀ fun apania.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo rí Éfúráímù bí ìlú Tírúsì tí a tẹ̀dó sí ibi dáradára ṣùgbọ́n Éfúráímù yóò kó àwọn ọmọ rẹ̀ jáde fún àwọn apànìyàn.”