Hosea 9:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli kò ní dúró ní ilẹ̀ OLUWA mọ́; Efuraimu yóo pada sí Ijipti, wọn yóo sì jẹ ohun àìmọ́ ní ilẹ̀ Asiria.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kì yio gbe inu ilẹ Oluwa; ṣugbọn Efraimu yio padà si Egipti, nwọn o si jẹ ohun aimọ́ ni Assiria.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn kò ní ṣẹ́kù sí ilé OLÚWA Éfúráímù yóò padà sí Éjíbítì Yóò sì jẹ oúnjẹ àìmọ̀ ní Ásíríà.