Isaiah 10:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ohun tí yóo kù ninu àwọn igi igbó rẹ̀ kò ní ju ohun tí ọmọde lè kà, kí ó sì kọ sílẹ̀ lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iyokù igi igbó rẹ̀ yio si jẹ diẹ, ti ọmọde yio le kọwe wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn igi tí yóò kù nínú igbóo rẹ̀ yóò kéré níye, tí ọ̀dọ́mọdé yóò fi le kọ̀ wọ́n sílẹ̀.