Isaiah 10:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
wọ́n ń dínà ìdájọ́ òdodo fún àwọn aláìní, wọn kò sì jẹ́ kí àwọn talaka ààrin àwọn eniyan mi rí ẹ̀tọ́ wọn gbà, kí wọ́n lè sọ àwọn opó di ìkógun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati yi alaini kuro ni idajọ, ati lati mu ohun ẹtọ kuro lọwọ talakà enia mi, ki awọn opo ba le di ijẹ wọn, ati ki wọn ba le jà alainibaba li ole!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
láti dún àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọn àti láti fa ọwọ́ ìdájọ́ sẹ́yìn kúrò níwájú àwọn olùpọ́njú ènìyàn mi, wọ́n sọ àwọn ọ̀pọ̀ di ìjẹ fún wọn. Wọ́n sì ń ja àwọn aláìní lólè.