Isaiah 10:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ọjọ́ náà, ìyókù Israẹli ati àwọn tí yóo yè ní agbo ilé Jakọbu, kò ní gbé ara lé ẹni tí ó ṣá wọn lọ́gbẹ́ mọ́, ṣugbọn OLUWA, Ẹni Mímọ́ Israẹli ni wọn óo fẹ̀yìn tì ní òtítọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe li ọjọ na, iyokù Israeli, ati iru awọn ti o salà ni ile Jakobu, ki yio tun duro tì ẹniti o lù wọn mọ; ṣugbọn nwọn o duro tì Oluwa, Ẹni-Mimọ Israeli, li otitọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ijọ́ náà, àwọn tí ó ṣẹ́kù ní Ísírẹ́lì Àwọn tí ó yè ní ilée Jákọ́bù kò ní gbẹ́kẹ̀lé ẹni náà tí ó lùwọ́n bolẹ̀ ṣùgbọ́n yóò gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì.