Isaiah 10:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Israẹli, bí àwọn eniyan rẹ tilẹ̀ pọ̀ bí iyanrìn etí òkun, díẹ̀ ninu wọn ni yóo pada, nítorí ìparun ti di òfin ó sì kún fún òdodo
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi Israeli enia rẹ ba dàbi iyanrìn okun, sibẹ iyokù ninu wọn o pada: aṣẹ iparun na yio kun àkúnwọ́sílẹ̀ ninu ododo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn an rẹ, ìwọ Ísírẹ́lì dàbí yanrìn ní òkun, ẹni díẹ̀ ni yóò padà. A ti pàṣẹ ìparun à kún wọ́ sílẹ̀ àti òdodo.