Isaiah 10:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n sọdá sí òdìkejì odò wọ́n sùn ní Geba di ọjọ́ keji. Àwọn ará Rama ń wárìrì, àwọn ará Gibea, ìlú Saulu sá lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti rekọja ọ̀na na: nwọn ti wọ̀ ni Geba; Rama bẹ̀ru; Gibea ti Saulu sá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ti rékọjá ọ̀nà, wọ́n wí pé, “Àwa ó tẹ̀dó sí Gébà lóru yìí.” Rámà mì tìtì Gíbíà ti Ṣọ́ọ̀lù sá lọ.