Isaiah 10:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Madimena ń sá lọ, àwọn ará Gebimu ń sá àsálà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A ṣi Madmena nipo dà; awọn ara Gebimu ko ara wọn jọ lati sa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mádíménà ti fẹṣẹ̀ fẹ́ ẹ Àwọn ènìyàn Gébímù ti farapamọ́.
Recommended Reading