Isaiah 10:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní òní olónìí, yóo dúró ní Nobu, yóo di ọwọ́ rẹ̀ sí àwọn òkè Sioni, àní òkè Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio duro sibẹ ni Nobu li ọjọ na: on o si mì ọwọ́ rẹ̀ si oke giga ọmọbinrin Sioni, oke kekere Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ yìí, wọn yóò dúró ní Nóbù wọn yóò kan sáárá, ní òkè ọmọbìnrin Ṣíhónì ní òkè Jérúsálẹ́mù.