Isaiah 10:34 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Yóo fi àáké gé àwọn igi igbó tí ó dí, Lẹbanoni pẹlu gbogbo igi ńláńlá rẹ̀ yóo sì wó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si fi irin ke pantiri igbó lu ilẹ, Lebanoni yio si ṣubu nipa alagbara kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun yóò gé igbó dídí pẹ̀lú àáké, Lẹ́bánónì yóò ṣubú níwájú Alágbára náà.