Isaiah 10:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Háà! Asiria! Orílẹ̀-èdè tí mò ń lò bíi kùmọ̀, ati bíi ọ̀pá nígbà tí inú bá bí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun Assuri, ọgọ ibinu mi, ati ọ̀pa ọwọ́ wọn ni irúnu mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ègbé ni fún àwọn ará Ásíríà, ọ̀gọ ìbínú mi, ní ọwọ́ ẹni tí kùmọ̀ ìbínú mi wà!