Isaiah 10:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí ó wí pé: “Ṣebí ọba ni gbogbo àwọn olórí ogun mi!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori o wipe, Ọba kọ awọn ọmọ-alade mi ha jẹ patapata?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
‘Kì í haá ṣe pé ọba ni gbogbo àwọn aláṣẹ mi?’ ni Olúwa wí.

Recommended Reading