Isaiah 13:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A óo so àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀ lójú wọn, a óo kó ilé wọn, a óo sì bá àwọn obinrin wọn lòpọ̀ pẹlu agbára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ wọn pẹlu li a o fọ́ tũtu loju ara wọn; a o si kó wọn ni ile, a o si fi agbara bà obinrin wọn jẹ́;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn mọ̀jèsín wọn ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn, gbogbo ilẹ̀ wọn ni a ó kó àwọn aya wọn ni a ó sì bá dàpọ̀.