Isaiah 13:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ ta àsíá ní orí òkè gíga, ẹ gbóhùn sókè sí wọn. Ẹ juwọ́, kí àwọn ológun gba ẹnu ibodè àwọn ọlọ́lá wọlé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ gbe ọpágun soke lori oke giga, ẹ kọ si wọn, ẹ juwọ, ki nwọn ba le lọ sinu ẹnu-odi awọn ọlọla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbé àṣíá ṣókè ní orí òkè gbẹrẹfu, kígbe sí wọn, pè wọ́n láti wọlé sí ẹnu ọ̀nà àwọn Bọ̀rọ̀kìnní.