Isaiah 13:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀ láti ìran dé ìran, àwọn ará Arabia kankan kò ní pa àgọ́ sibẹ, bẹ́ẹ̀ ni àwọn darandaran kankan kò ní jẹ́ kí agbo aguntan wọn sinmi níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kì yio tẹ̀ ẹ dó mọ, bẹ̃ni a kì yio si gbe ibẹ̀ mọ lati irandiran: bẹ̃ni awọn ara Arabia kì yio pagọ nibẹ mọ; bẹ̃ni awọn oluṣọ-agutan kì yio kọ́ agbo wọn nibẹ mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kì yóò sì gbé ibẹ̀ mọ́ tàbí kí á gbé inú rẹ̀ láti ìrandíran; Árábù kan yóò fi àgọ́ rẹ lélẹ̀ níbẹ̀, Olùsọ́ àgùntàn kan kì yóò kó ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀.