Isaiah 13:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ìkookò yóo máa ké ninu ilé ìṣọ́ rẹ̀, ààfin rẹ̀ yóo di ibùgbé àwọn ajáko, àkókò rẹ̀ súnmọ́ etílé, ọjọ́ rẹ̀ kò sì ní pẹ́ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọ̀wawa yio si ma ke ninu ãfin wọn, ati dragoni ninu gbọ̀ngàn wọn daradara: ìgba rẹ̀ si sunmọ etile, a kì yio si fa ọjọ rẹ̀ gùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìkookò yóò máa gbó ní ibùba wọn, àwọn ajáko nínú arẹwà ààfin wọn.