Isaiah 13:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Èmi pàápàá ti pàṣẹ fún àwọn tí mo yà sọ́tọ̀, mo ti pe àwọn akọni mi, tí mo fi ń yangàn, láti fi ibinu mi hàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti paṣẹ fun awọn temi ti a yà si mimọ́, emi ti pe awọn alagbara mi pẹlu fun ibinu mi, ani awọn ti nwọn yọ̀ ninu ọlanla mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo ti pàṣẹ fún àwọn ẹni mímọ́ mi, mo ti pe àwọn jagunjagun mi láti gbé ìbínú mi jáde àwọn tí ń yọ̀ nínú ìṣẹ́gun mi.