Isaiah 13:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n wá láti ilẹ̀ òkèèrè, láti ìpẹ̀kun ayé. OLUWA ń bọ̀ pẹlu àwọn ohun ìjà ibinu rẹ̀, tí yóo fi pa gbogbo ayé run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti ilẹ okerè wá, lati ipẹkun ọrun, ani, Oluwa, ati ohun-elò ibinu rẹ̀, lati pa gbogbo ilẹ run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n wá láti ọ̀nà jínjìn réré, láti ìpẹ̀kun ọ̀run wá OLÚWA pẹ̀lú àwọn ohun ìjà ìbínú un rẹ̀— láti pa gbogbo orílẹ̀ èdè náà run.