Isaiah 14:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo ọba àwọn orílẹ̀-èdè dùbúlẹ̀ ninu ògo wọn olukuluku ninu ibojì tirẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo ọba awọn orilẹ-ède, ani gbogbo wọn, dubulẹ ninu ogo, olukuluku ninu ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ọba orílẹ̀ èdè ni a tẹ́ sílẹ̀ ọ̀kọ̀ọ̀kan nínú ibojì tirẹ̀.