Isaiah 14:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ múra láti pa àwọn ọmọ rẹ̀ run nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wọn, kí wọn má baà tún gbógun dìde, kí wọn gba gbogbo ayé kan, kí wọn sì kọ́ ọpọlọpọ ìlú sórí ilẹ̀ ayé.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mura ibi pipa fun awọn ọmọ rẹ̀, nitori aiṣedẽde awọn baba wọn; ki nwọn ki o má ba dide, ki nwọn ni ilẹ na, ki nwọn má si fi ilu-nla kun oju aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tọ́jú ibìkan tí a ó ti pa àwọn ọmọkùnrin rẹ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńláa wọn, wọn kò gbọdọ̀ dìde láti jogún ilẹ̀ kí wọ́n sì bo orí ilẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìlúu wọn.