Isaiah 14:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èsì wo ni a óo fún àwọn ikọ̀ orílẹ̀-èdè Filistini? A óo sọ fún wọn pé, “OLUWA ti fi ìdí Sioni sọlẹ̀ àwọn tí à ń pọ́n lójú láàrin àwọn eniyan rẹ̀ yóo fi ibẹ̀ ṣe ibi ààbò.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Èsi wo li a o fi fun awọn ikọ̀ orilẹ-ède? Pe, Oluwa ti tẹ̀ Sioni dó, talaka ninu awọn enia rẹ̀ yio si sá wọ̀ inu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ni ìdáhùn tí a ó fún agbẹnusọ orílẹ̀ èdè náà? “OLÚWA ti fi ìdí Ṣíhónì kalẹ̀, àti nínú un rẹ̀ ni àwọn ènìyàn rẹ̀ tí a ti pọ́nlójú yóò ti rí ààbò o wọn.”

Recommended Reading