Isaiah 14:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn igi Sipirẹsi ń yọ̀ yín; àwọn igi Kedari ti Lẹbanoni sì ń sọ pé, ‘Láti ìgbà tí a ti rẹ ọba Babiloni sílẹ̀, kò sí agégi kan tí ó wá dààmú wa mọ́.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ, igi firi nyọ̀ ọ, ati igi kedari ti Lebanoni, wipe, Lati ìgba ti iwọ ti dubulẹ, kò si akegi ti o tọ̀ wa wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú pẹ̀lù àwọn igi Páínì àti àwọn igi kédárì ti Lẹ́bánónì ń yọ̀ lóríì rẹ ó wí pé, “Níwọ̀n bí a ti rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ báyìí, kò sí alagi tí yóò wá láti gé wa lulẹ̀.”