Isaiah 15:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà àwọn ohun tí wọ́n ní lọpọlọpọ ati ohun ìní tí wọn ti kó jọ, ni wọ́n kó lọ sí ìkọjá odò Wilo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ọ̀pọ eyi ti nwọn ti ni, ati eyi ti nwọn ti kojọ, ni nwọn o gbe kọja odò willo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí gbogbo ọrọ̀ tí wọ́n ti ní tí wọ́n sì tòjọ wọ́n ti kó wọn kọjá lọ lóríi gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ odò pópúlárì.