Isaiah 15:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ariwo kan ti gba gbogbo ilẹ̀ Moabu kan, ẹkún náà dé Egilaimu, ìpohùnréré náà sì dé Beerelimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori igbe na ti yi agbegbè Moabu ka; igbe na si de Eglaimu, ati igbe na de Beerelimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbohùngbohùn ń gba igbe wọn dé ìpẹ̀kun ilẹ̀ Móábù; ìpohùnréré wọn lọ títí dé Ẹgíláémù, igbe ẹkún wọn ni a gbọ́ títí dé kànga Élímù.