Isaiah 15:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí odò Diboni kún fún ẹ̀jẹ̀, sibẹsibẹ n óo jẹ́ kí ohun tí ó jù bẹ́ẹ̀ lọ dé bá a. Kinniun ni yóo pa àwọn ará Moabu tí ó bá ń sá lọ ati àwọn eniyan tí ó bá kù ní ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori odò Dimoni yio kún fun ẹ̀jẹ: nitori emi o fi ibi miran sori Dimoni, emi o mu kiniun wá sori ẹniti ó sálà kuro ni Moabu, ati lori awọn ti o kù ni ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Omi Dímónì kún fún ẹ̀jẹ̀, ṣíbẹ̀ èmi ó tún mu ohun tí ó jù báyìí lọ wá sórí Dímónì— kìnnìún kan wá ṣórí àwọn ìṣáǹṣá Móábù àti lórí àwọn tí ó tún ṣẹ́kù sórí ilẹ̀ náà.