Isaiah 16:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ti kó àgbò láti Sela, ní ọ̀nà aṣálẹ̀, wọ́n fi ranṣẹ sí aláṣẹ ilẹ̀ náà, ní òkè Sioni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ rán ọdọ-agutan si alakoso ilẹ lati Sela wá si aginju, si oke ọmọbinrin Sioni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi ọ̀dọ́-àgùntàn ṣe ẹ̀bùn ránṣẹ́ sí aláṣẹ ilẹ̀ náà, Láti Ṣẹ́là, kọjá ní ihà, lọ sí orí òkè ọ̀dọ́mọbìnrin Ṣíhónì.