Isaiah 16:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Moabu bá wá siwaju, tí ó fi gbogbo agbára gbadura ninu ilé oriṣa rẹ̀, títí ó fi rẹ̀ ẹ́, adura rẹ̀ kò ní gbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe, nigbati a ba ri pe ãrẹ̀ mú Moabu ni ibi giga, ni yio wá si ibi-mimọ́ rẹ̀ lati gbadura; ṣugbọn kì yio bori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Móábù farahàn ní ibi gíga rẹ̀, ó ṣe ara rẹ̀ ní wàhálà lásán; Nígbà tí ó lọ sí ojúbọ rẹ̀ láti gbàdúrà òfo ni ó já sí.