Isaiah 16:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, kí Moabu máa pohùnréré ẹkún, kí gbogbo eniyan máa sun ẹkún arò ní Moabu. Wọn óo sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, nígbà tí wọn ba ranti àkàrà Kiri Heresi, tí ó ní èso àjàrà ninu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni Moabu yio hu fun Moabu, gbogbo wọn o hu: nitori ipilẹ Kir-haresi li ẹnyin o gbàwẹ; nitõtọ a lù wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni àwọn ará Móábù pohùnréré wọ́n jùmọ̀ pohùnréré lórí Móábù. Ṣunkún kí o sì banújẹ́ fún àwọn ọkùnrin ìlú Hárésétì.