Isaiah 17:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
wọn ìbáà hù lọ́jọ́ tí ẹ gbìn wọ́n, kí wọ́n yọ òdòdó ní òwúrọ̀ ọjọ́ tí ẹ lọ́ wọn sibẹsibẹ kò ní sí ìkórè ní ọjọ́ ìbànújẹ́ ati ìrora tí kò lóògùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ na ni iwọ o mu ki ọ̀gbin rẹ dàgba, ati li owurọ ni iwọ o mu ki irugbin rẹ rú: ṣugbọn a o mu ikorè lọ li ọjọ ini, ikãnu kikoro yio si wà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, bí ẹ tilẹ̀ mú àsàyàn igi tí ẹ sì gbin àjàrà tí ó ti òkèrè wá, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọjọ́ tí ẹ kó wọn jáde ẹ mú wọn hú jáde, àti ní òwúrọ̀ tí ẹ gbìn wọ́n ẹ mú kí wọ́n rúdí, ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ ìkóórè kò ní mú nǹkan wá ní ọjọ́ àrùn àti ìrora tí kò gbóògùn.