Isaiah 17:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbọ́ ariwo ọ̀pọ̀ eniyan, wọ́n ń hó bí ìgbì òkun. Ẹ gbọ́ ìró àwọn orílẹ̀-èdè wọ́n ń hó bíi ríru omi òkun ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbé ni fun ariwo ọ̀pọ enia, ti o pa ariwo bi ariwo okun; ati fun irọ́ awọn orilẹ-ède, ti nwọn rọ bi rirọ́ omi pupọ̀!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsii, ìrunú àwọn orílẹ̀ èdè— wọ́n ń runú bí ìgbì òkun! Kíyèsii, rògbòdìyàn tí ogunlọ́gọ̀ ènìyàn wọ́n bú ramúramù gẹ́gẹ́ bí ariwo odò ńlá!