Isaiah 17:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ìlú rẹ̀ yóo di àkọ̀tì títí lae wọn yóo di ibùjẹ àwọn ẹran, níbi tí àwọn ẹran yóo dùbúlẹ̀, tí ẹnikẹ́ni kò sì ní dẹ́rùbà wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kọ̀ gbogbo ilu Aroeri silẹ: nwọn o jẹ ti ọ̀wọ-ẹran, ti yio dubulẹ, ẹnikẹni kì yio dẹrubà wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìlú Áróérì ni a ó kọ̀ sílẹ̀ fún àwọn agbo ẹran tí yóò máa sùn ṣíbẹ̀, láìsí ẹni tí yóò dẹ́rùbà wọ́n.